Smiley face

Awon ika eniyan ti pa omo jayejaye to de lati Italy.

Awon amokunseka eda kan ti seku pa omokunrin omo Naijiria lati ipinle Edo leyin to de lati orileede Italo.

Omokunrin ti won pe oruko re ni Johnny ni awon rojo ota ibon fun ninu ile re to wa nipinle Eko.

Orisiirisii ibeere lo ti n jeyo bayii eleyii ti enikeni ko le dahun si?

Awon wo lo pa Johnny?
Kilode ti won fi pa a?
Se Italy ni won ti sanwo emi re n abi Naijiria?
Iru ise wo ni maanu na n se ni orileede Italy?

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment