Smiley face

Ohun tí àwon ènìyàn ṣe láti fojú kan Buhari ni Plateau bani lẹ́rù

In Plateau, kosi ohun tí awon ènìyàn kò ṣe tán láti fojú kan Buhari. Àwọn kan gùn orí igi, àwọn kan gùn ilé alájà, díẹ báyìí lo kù kí àwọn kan gorí òpó iná. Inú gbogbo ènìyàn ń dùn, a fi bí ìgbà ti Jésù padà wọ Jerúsálẹ́mù bẹẹ gẹlẹ ni àwọn ènìyàn ṣe n   fò sókè. 08/03/18

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment