Smiley face

City People Magazine ṣetán láti dá Adegbodu Twins lọ́lá

Awon Aláṣẹ City People Magazine tí ṣetan láti ṣe ayẹyẹ idalọla fún àwọn ìbejì Adegbodu fún ipa ribiribi tí wón tí kò ti a ba n sọ nípa ojúlówó orín ẹ̀mí to ni ìtumò. Ìlú Èkó ni ayeye naa yoo ti wáyé lọjọ kẹtàlá oṣù karùn-ún ọdún táa wáyé. Ẹyin naa le pe awon ìbejì yìí lórí 0803 713 2152 láti bá wọn yọ fún. Oriire na. Ire a kárí ó!
#Congratulations

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment