Oni (December 31) ni ojo ibi Femi Adebayo ati Odunlade Adekola, awon agbaoje onise tiata ti ko se fowo ro seyin nigba kankan.
Read More
Home / Amuludun
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Showing posts with label Amuludun. Show all posts
Idi ti Kemi Olunlọyọ fi pe baba re ni ALAINILAAKAYE ẹda
Kemi Omololu-Olunloyo Ò ní kọ layé ti mọ Kemi Olunlọyọ gẹgẹ bi oniroyin kan ti ki i ye da awuyewuye silẹ ni akoko ti isẹ iroyi...
Read More
Seun Egbegbe ti salọ siluu Malaysia leyin asiri jibiti $3000 tuntun
Seun Egbegbe Ohun ti a gbọ bayii ni wi pe Seun Egbegbe ti gbera lọ siluu Malaysia. Ti ẹ ko ba gbagbe, lẹyin ẹsun ole jija ti won fi k...
Read More
Princess Elizabeth Onanuga: Isẹ kekere kọ ni Boss Lady ati Toke Omo London
Princess Elizabeth Onanuga Ọjọ Kẹwaa osu kokanla odun yii ni orekelẹwa naa wa sori eto Gbedemuke nibi to ti n se alaye nipa awon ak...
Read More
Princess Elizabeth Onanuga: Irawọ osere ti won wo ni United Kingdom
Princess Elizabeth Onanuga Aimoye ẹyẹ lo n kọrin nigbo, sugbọn ọtọ ni tẹyẹ àwoko. Eniyan le fi ologbo se apejuwe amọtẹkun, sugbon g...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)