Àwọn adigunjale wọ ilu Offa lọjọ karùn-ún oṣù kẹrin ọdún yìí láti fọ banki. Àìmọye èmi lo ṣòfò, lára wọn ni ọlọ́pàá àti àwọn obìnrin. ...
Read More
Home / Iroyin
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Ohun tí àwon olopaa ṣe fún ìyá àgbàlagbà ni Abia ni yii
Tí bá ń sọ nípa àwọn tí wọn wù ìwà ibajẹ, ó yẹ ká sọ nípa àwọn ọmọlúwàbí pẹ̀lú. Ní ìpínlè Abia, ìyá àgbàlagbà to ń bọ láti oko dá ẹyìn rẹ nù...
Read More
Gómìnà ipínlẹ̀ Kano fi ori ru iyẹ̀pẹ̀ lónìí
Ẹnu yà ọ̀pọ̀lọpọ̀ lónìí nígbà tí gómìnà ipínlẹ̀ Kano, Abdullahi Ganduje, ṣe abewo si ise àkànṣe kan tí ń lọ lọ́wọ́. Gómìnà rí àwọn ènìyàn t...
Read More
"Emir kìí se èdè Hausa", àlàyé Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi tí ṣàlàyé ohun tó rújú
Ọ̀jọ̀gbọ́n Farooq Kperogi ọmọ Nàìjíríà tí ń sise olùkọ́ni ni ilu America tí ṣàlàyé wí pé, ìkà àbùkù nínà láàárín Yorùbá àti Haúsá láti ìgbà...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)