Àìmọye èmi ni Boko Haram kò bá rán lọ sọ́run lópin ọsẹ tó kọjá yìí, 20/05/2018, níbi wọn ti n gbìyànjú láti dáná bombu 💣 sì mọsa...
Read More
Home / Iroyin
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Showing posts with label Iroyin. Show all posts
Dangote tí bẹ̀rẹ̀ si ni ṣe moto Peugeot jáde báyìí
Alhaji Aliko Dangote, ènìyàn dúdú to lowo ju lagbaye tí ṣetan báyìí láti má ṣe àwọn ọkọ pijó jáde ní ìlú Kaduna. Dangote Peugeot Automobile ...
Read More
Àwọn ará ìlú ṣe ayẹyẹ ọjọ́ ìbí fún ọlọ́pàá "yellow fever" olótìítọ́
Àsegbé kan kò sì láyé, àsepamọ́ ló wà. Ọkùnrin tí orúkọ n jẹ Ifedioranma Darlington tí ń sisẹ́ adari ọkọ̀ ojú pópónà ni ìkòríta Aroma nílùú...
Read More
Báyìí ni Ìyá Dare onigbin ṣe pàdé gómìnà, kositọma rẹ àtijọ́
"Mo má ń sọ fún àwọn ènìyàn wí pé Kositọma mi àtijọ́ ni gomina ṣùgbọ́n wọn kì í gba mi gbọ - Ìyá Dare onigbin ni Owena. Ó ti pe tí Ìyá...
Read More
Ìrìn àjò wákàtí kan: Ọkọ̀ ojú irin Ibadan d'Eko ti fẹ́ parí - Kongila
Ìṣe ń lọ lọ́wọ́ báyìí nípa ìṣe ọna ojú-irin tí reluwe yóò má rìn láàárín ìlú Èkó sì ìlú Ìbàdàn. Àwọn agbase ṣe náà so wí pé, oṣù Kejìlá ọdún...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)