Adari ọmọ ẹgbẹ́ to pọ̀ jù lọ nílé ìgbìmọ̀ aṣojú sofin Abuja, Femi Gbaja ṣe ajọyọ pẹ̀lú aya rẹ, Yemisi Gbaja, pẹ̀lú bo se pe ẹni àádọ́ta ọdún...
Read More
Home / Gbajumo Lawujo
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
Showing posts with label Gbajumo Lawujo. Show all posts
Ká mú tẹ̀gàn kúrò, Telu rẹwà lọkunrin
Kò sí ohun tó burú láti nawọ́ ìfẹ́ si àwọn ẹ̀yà to kú lórílẹ̀ Nàìjíríà 🇳🇬 , sebi ọkàn náà ni gbogbo wa. Ṣùgbọ́n gẹ́g...
Read More
Ohun tí Muyiwa Ademola sọ nípa orekelẹwa aya rẹ ni yìí
"Olólùfẹ́ mi, aya mi, Akankẹ mi, bí mo bá wà sílè ilé ayé nígbà igba, ìwọ kan náà lọ má jẹ aya mi. Àìmọye ìdùnnú lọ fún mi ti mi ò lé r...
Read More
Oludasilẹ Facebook, Mark Zuckerberg pé ẹni ọdún mẹ́rinlelọgbon (34) lónìí
Òní, 17/05/18, ni ọjọ́ ìbí oludasile Facebook, Mark Zuckerberg, eléyìí tí gbogbo wa njẹ àǹfààní rẹ lónìí. Kí n tó kí Mark fún ayẹyẹ ọjọ́ ì...
Read More
Happy Birthday Oluwafunke Etti
Òní ni ọjọ́ ìbí osere òní tíátà, Funke Etti. Igba ọdún, ọdún kan ni. Àṣẹ
Read More
Happy Birthday olùkọ́ mi: Apènà pé léèyàn
Ẹ bá ma kí Apena, ẹ bá mi sọ fún olùkọ́ mi wí pé Olayemi mo wọn léèyàn pàtàkì. Bí ó bá lo igba ọdún láyé, ọdún kan ni wọn o fi ka fún ọ lóde...
Read More
Happy Birthday! Mama Kunle Afolayan pé ní ọdún márùndínlọ́gọ́rin (75)
Mama Kunle Afolayan pé ẹni odùn márùndínlọ́gọ́rin láyé. A gbàdúrà ire àlàáfíà, ìdùnnú àti èmi gigùn fún mama. Igba ọdún, ọdún kan ni. Ha...
Read More
O ti jasire: Bukola Oni tí diyàwó tuntun
Mi ò lọrẹ to pò, díẹ ni àwọn ọrẹ mi; lára wọn sì ni Bukky wá. Bukky a má lo inú kan, ó nifẹ àwọn ènìyàn, bákan ló jẹ́ akíkanjú obìnrin. Mo...
Read More
Ènìyàn bí Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi
Rev. Mother Esther Abimbola Ajayi, adari ijo Love Of Christ Generation C&S to wá ni Clapham nílùú London ni ènìyàn pàtàkì wa fún ọsẹ ...
Read More
#HappyBirthday Joke Muyiwa: Olùkọ́ àgbà iṣẹ́ tíátà tó pedegé!
Àyàfi ti ènìyàn bá fẹ fi gba kan bọkan nínú ni yóò sọ wí pé Joke Muyiwa kii se agbaoje nínú ìṣe tíátà. Se àgbékalẹ̀ ni ka sọ ní àbí èdè líl...
Read More
Áńgẹ́lì kan tí ń jẹ Lára Olubo
Òní, 15/03/18, ní ọjọ́ ìbí ogbontarigi sọrọsọrọ orí afẹ́fẹ́, Lára Olubo. Arábìnrin Lara jẹ́ akíkanjú ènìyàn eléyìí tí kìí fi ìṣe rẹ ṣeré. ...
Read More
#HappyBirthday Aduke: Adenike tí gòkè odò káfárá to ja!
Olójú ènìyàn tó pé láì lábùkù. Olójú onisẹ ọpọlọ tí ò kù síbì kan . Àyàfi ẹni Oluwa bá dalọla. Ayafi Aduke t'Èdùmàrè gbé ga lójijì. ...
Read More
Happy Birthday Prof: Ènìyàn bí Yemi Osinbajo wón bí oju
E má jẹ ki n parọ fún yín. Lára ona kan pàtàkì lati se àkíyèsí bóyá ènìyàn jẹ ọlọ́gbọ́n tàbí bẹẹkọ ni nípa fi fún ẹni bẹẹ láàyè láti sọ ọrọ ...
Read More
Happy Birthday Prof: Ènìyàn bí Yemi Osinbajo wón bí oju
E má jẹ ki n parọ fún yín. Lára ona kan pàtàkì lati se àkíyèsí bóyá ènìyàn jẹ ọlọ́gbọ́n tàbí bẹẹkọ ni nípa fi fún ẹni bẹẹ láàyè láti sọ ọrọ ...
Read More
"Ìdí tí oṣù kejì ọdún fi ṣe pàtàkì sì mi" - Olajumoke ọmọ oniburedi
"Oṣù kejì ọdún je àkókò ìyanu àti àgbàrá Ọlọ́run láyé mi. Nínú oṣù yìí ni ori gbemi pade TY Bello to fi Camera 📸 rẹ gbà os...
Read More
#HappyBirthday Afeez Eniola Onílé Eré
Èdùmàrè lo ń gbé ènìyàn ga, ọgbọ́n orí kọ. Ẹni mbẹ laye kò dúpẹ́, àìmọye ènìyàn rere tó sún ni ó jí. Gbogbo wa là bá Afeez Eniola yo lónìí...
Read More
Ènìyàn pàtàkì bí Lara Olubo: Ọbabirin Sorosoro Agbaye
Bí ènìyàn bá semi loore mo ti ṣèlérí wí pé mi ò ní gbàgbé. Ọjọ́ tí mo n wà ènìyàn kan ṣoṣo láti dúró fún mi. Lara Olubo dúró fún mi lọ́nà m...
Read More
Òní ni ojo ibi Dúpẹ́ Odulate ìyàwó Babatee
Aya rere lọọdẹ ọkọ. #HappyBirthday
Read More
#HappyBirthday Yinka Ayefele Ọba Tungba Gospel
Olayinka Joel Ayefele le lodun lónìí ọjọ́ kinni oṣù kejì ọdún. Igba ọdún, ọdún kan ni. Ire.
Read More
#HappyBirthday Yemi Sholade Agba Akin
Gbogbo wa là bá Ogbeni Yemi Sholade yọ pelu bí osere náà ṣe lè lọ́dún. Ìgbà ọdún, ọdún kan ni. Àṣẹ
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)