Titi di akoko yii, enikeni ko le so pato ohun to sekupa oludije ipo gomina labe egbe oselu APC ni ipinle Kogi, Abubakar Audu. Se ise aye...
Read More
Home / Iroyin Kayeefi
Showing posts with label Iroyin Kayeefi. Show all posts
Showing posts with label Iroyin Kayeefi. Show all posts
Iyanu: E wo ohun ti won fi ibeji da lara
Nje e le biliifu eleyii? Awon ibeji okunrin meji fe awon ibeji obirin kan naa. Awon pasito meji to so won po, ibeji ni won. Awon ...
Read More
Awon omo Iraq n fi obe ge ori ara won nibi won ti n gbadura
Awon omo orileede Iraq ti won sin orisii esin musulumi kan ti n je "Shia Islam" n fi obe ge awo ori ara won nibi won ti n g...
Read More
Maanu Ti Nnkan Omokunrin Re Tobi Ju Ni Yii: "Opa Mose" Re Dabi Sanda Awon Fulani
Maanu ti won ni nnkan omokunrin re tobi ju lasiko yii ni yii gege bi iroyin agbaye TMZ se se afihan re. Roberto Esquivel Cabrera, eni ...
Read More
Milionu Mefa Ti Gbe Omo Naijeria Wonu Ese-Mefa: Ojukokoro Ti Pa Chukwudi!
Chukwudi, omo odun mejidinlogbon (28)ti padanu emi re leyin igba to ta kidinrin re ni milionu mefa owo naira (N6million)niluu Malaysia ...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)