Owusu pada iku ojiji lojo odun ileya Olayemi Oniroyin 9/06/2017 01:14:00 pm Add Comment Edit Omokunrin kan lo ti koja lo sorun niluu Ghana nibi oun ati awon ore re ti n se faaji odun ileya to koja. Alaye oro ni yii lati owo Ci... Read More
Abiyamo gbe ibi omo (placenta) kana Olayemi Oniroyin 5/04/2017 10:04:00 pm Add Comment Edit Airin jina lai ri abuke okere; ti eniyan ba rin titi yoo ri ibi ti won ti n fodo ibile jeun. Ohun ara to tun seyo lori ayelujara ni... Read More
Aye Akamara: Leyin 21yrs to ti n wa omo, odun meta lo tun fi ru oyun akobi re Olayemi Oniroyin 3/26/2017 10:10:00 am Add Comment Edit Eniyan to ba ni ko saye, won ti "sample" e ri ni. Errk. Gege bi Olanrewaju Adepoju se so ninu ewi re, oni eni aye ba da... Read More
Opin aye ti de: Awon obirin meji ti won fe ara won ti bo si gbangba Olayemi Oniroyin 3/26/2017 09:55:00 am Add Comment Edit Awon obirin meji yi, Parpistud ati Lawrencia Aligasi ti won gbe ni ilu Warri la gbo wi pe won jo fe ara won bi tokotaya. Oju ko ... Read More
Foto obirin ti won ge ori re ni Badagry ni yii Olayemi Oniroyin 3/23/2017 04:58:00 pm Add Comment Edit Arabirin yii ni ogbeni Taofik ti inagije re n je Kie-Kie seku pa ni agbegbe Badagry to wa niluu Eko lojo Aiku to koja(19:03:17) ... Read More