Nje e mo nipa ijamba to le sele nipa iwa ibaje oju popo? Olayemi Oniroyin 6/06/2017 11:25:00 pm Add Comment Edit Duro na ọ ga dirẹba, Ani ẹyin ni mo n ba wi sẹ, hẹn, ẹyin naa ni, awako oju ona ti rufin ijọba. Jọọ sare damilohun ibeere mi ni ... Read More
[Foto] Swagger ni Kemi Olunloyo gbe jade lati inu ewon lonii Olayemi Oniroyin 6/05/2017 10:51:00 pm Add Comment Edit Pelu idunnu ati ayo ni Kemi Olunloyo fi jade lonii nigba ti won tu sile logba ewon to wa ni Pota. Arabirin oniroyin ayelujara yii ni... Read More
Won ti dana sun okan lara awon omo eyin baddo ti n da Ikorodu laamu. Olayemi Oniroyin 6/05/2017 01:47:00 pm Add Comment Edit Ohun a ti gbo bayii ni wi pe, okan lara awon omo eyin baddo ti won sise ibi ni agbegbe Ikorodu to wa niluu Eko ni awon ara ilu ti dana s... Read More
Awon asewo meji ti pa Adeyinka leyin to je "dodo" tan nipinle Ogun Olayemi Oniroyin 5/31/2017 10:43:00 pm Add Comment Edit Okunrin kan ti oruko re n je Adeyinka Olayinka ni awon asewo ti gun nigo pa ni ile itura KS Hotel to wa ni Ifo. Adeyinka lo se agbesun... Read More
E wa oko Rolls Royce ti won se niluu Naijiria Olayemi Oniroyin 5/06/2017 03:33:00 pm Add Comment Edit Aimoye olopolo ati onilaakaye eda ni Olorun fi ta ile Naijiria lore, kosi sohun to ni ki Naija ma wa ninu awon ilu to ti goke lagbaye.... Read More