Buhari tí fò lọ sí orile-ede Ethiopia fún ìpàdé AU Olayemi Oniroyin 1/26/2018 06:34:00 pm Add Comment Edit Aare Muhammadu Buhari tí gbéra lọ sí orile-ede Ethiopia fún ìpàdé àjọ African Union ti yóò wáyé lonii ọjọ kerindinlogbon oṣù kinni odun 2018... Read More
Àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ APC Yibo tí ni kí eégún Buhari má jo lọ Olayemi Oniroyin 1/25/2018 10:43:00 pm Add Comment Edit Àwọn aṣáájú ẹgbẹ́ APC láti ilẹ Yibo tí kéde atileyin wọn fún Ààre Buhari láti díje ipò aare eleekeji Read More
Ko saaye fún Buhari lẹẹkan sii - Ebora ìlú Òwu Olayemi Oniroyin 1/25/2018 08:41:00 pm Add Comment Edit "Ko ba dára kí Buhari topàṣẹ iyì àti apọnle, ko má gbìyànjú láti gbé àpótí idibo eleekeji" - Obasanjo kilo fún Buhari nínú leta tu... Read More
Ohun tí Obasanjo gbàgbé kò fi sínú lẹta rẹ -Reuben Abati Olayemi Oniroyin 1/25/2018 08:18:00 pm Add Comment Edit "Obasanjo gbìyànjú nípa bó se menuba kudiẹkudiẹ isejoba Buhari. Ṣùgbọ́n ohun kan tó gbàgbé láti kó sínú leta rẹ ni, titorọ aforiji lọ́w... Read More
Obasanjo tí padà sórí leta to fi sangi mọ Jónátánì lori Olayemi Oniroyin 1/25/2018 07:57:00 pm Add Comment Edit Nígbà tí Obasanjo fe jarawo Jónátánì, leta yìí náà ni. Igba to ṣe odidi ìwé lo kan mọ àgbélébùú ayérayé. Buhari, má sọra ilẹ̀ ń yọ! Read More