Senator Mustapha Bukar tí parí isẹ rẹ nílùú Abuja. Wọn tí fi bàálù gbé padà sí ìlú rẹ, Katsina. Kí Ọlọ́run Allah bá dárí gbogbo aise dééde ...
Read More
Home / Oro Oselu
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts
Showing posts with label Oro Oselu. Show all posts

Kositọma dáadáa ní Buhari - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá
"Kositọma dáadáa ní Buhari . Mo fọwọ́ síi kò padà wa nígbà kejì láti wá parí àwọn iṣẹ́ takuntakun tó ti bẹ̀rẹ̀ - Aláké tilẹ Ẹ̀gbá Oba A...
Read More
Ìdìbò kú oṣù mewaa, asofin méjì kú láàárín ọsẹ meji
Lẹ́yìn bí ọsẹ kan tí ọmọ ilẹ̀ igbimo aṣojú sofin n kan kù, Senator míì tún kù ní àárọ̀ òní ni ilu Abuja. Senator Mustapha Bukar to wá láti i...
Read More

Omoyele Sowore wọlé sí Naija pelu òkìkí nla
Àìmọye lọ tú jáde lónìí láti kí Omoyele Sowore , Olóòtú ìwé Ìròyìn Sahara Reporters , ẹni tó setan láti díje fún ipò ààrẹ kaabọ sì orileede ...
Read More

Orin òwe, orín ọtẹ, orín Sai Buhari tí gba gbogbo Bauchi báyìí
Ni ìpínlẹ̀ Bauchi wọn kó Buhari jẹ́ bí "abinci". Lọja Satide to kọjá yìí ni èrò bí èrò mecca tú jáde láti yọ ayọ̀ ọdún mẹta tí Sa...
Read More
Subscribe to:
Posts
(
Atom
)