Àkúrẹ́ mi tìtì: Òkìkí Omoyele Sowore ń lọ sókè sí ní joojumọ Olayemi Oniroyin 4/24/2018 11:38:00 pm Add Comment Edit Ènìyàn tí kò dá nílé kò lè dá níta. Àìmọye àwọn ènìyàn lọ wà pàdé Omoyele Sowore, ẹni tí ń ṣe ọmọ ipínlẹ̀ Ondo, ni papakọ ofurufu ìlú Àkúré ... Read More
Omoyele Sowore ṣe àbẹ̀wò sì Deji tiluu Àkúré Olayemi Oniroyin 4/24/2018 11:20:00 pm Add Comment Edit Oludije fún ipò aare lodun 2019, Ogbeni Omoyele Sowore ṣe àbẹ̀wò sì Deji tiluu Àkúré Read More
"Ìyẹ́ ni wọn o má wo lẹ́yìn ẹyẹ, wọn ò lẹ́yẹ mu"- Dino Melaye ń fọ lẹ́yìn to bọ lọ́wọ́ kondo ọlọ́pàá laarọ yìí nílùú Abuja Olayemi Oniroyin 4/23/2018 02:22:00 pm Add Comment Edit "Ìyẹ́ ni wọn o má wo lẹ́yìn ẹyẹ, wọn ò lẹ́yẹ mu"- Dino Melaye ń fọ lẹ́yìn to bọ lọ́wọ́ kondo ọlọ́pàá laarọ yìí nílùú Abuja. Àárọ̀... Read More
Ilu Awolowo setan láti gbalejo Omoyele Sowore Olayemi Oniroyin 4/23/2018 01:16:00 pm Add Comment Edit #TakeItBack Read More
Àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege to kò àwọn ọmọ ìta wọlé igbimo asofin Olayemi Oniroyin 4/19/2018 01:35:00 am Add Comment Edit Laarọ yìí ni àwọn ọmọ ìta yawọ ilé igbimo asofin àgbà Abuja tí wọn sì jí ọ̀pá àṣẹ sálọ. Ní báyìí àwọn ọlọ́pàá tí gbé Senator Ovie Omo Agege ... Read More