Mo fẹ́ràn láti máa kàwé. Orisirisi ìwé ni mo sì ti kà nípa òdòdó àti ìwúlò rẹ layika. Yàtọ̀ sí ẹ̀ṣọ́ ilé, fifi ojú kó òdòdó má n jẹ ki ènìy...
Read More
Home / Ọ̀rọ̀ Olóòtú
Showing posts with label Ọ̀rọ̀ Olóòtú. Show all posts
Showing posts with label Ọ̀rọ̀ Olóòtú. Show all posts
Funmilayo rin ihoho wọja, kò sinwin bẹẹ ni ò yà wèrè
Ẹni ja ìjàngbara kò yàtò ṣeni tí wọn forí rẹ fagbọn. Ẹni wọn forí rẹ fagbọn kìí dúró jẹ ẹ. Ayafi ẹni Olúwa bá ko yọ. Funmilayo RansomeKuti ...
Read More
Lẹta: "Ó ń semi bi kí n pa ara mi" - Obirin afẹsọna
Olayemi kíni mo lè ṣe? Ó ń ṣe mi bi kí n pa ara mi. Ọkùnrin tí èmi àti ẹ jọ ń fẹ́ ara wa bí ọdún kan sẹ́yìn, ní atí jọ ṣe ayẹyẹ introduction...
Read More
Ẹ polówó ọjà yín nibi: Irú ọjà wo lẹ́yìn ń tà?
Ni báyìí, àǹfààní tí wá fún yín láti ṣe ìkéde, ipolowo, ìpolongo lórí àwọn ìkànnì wá lórí ayélujára pẹlu irọrun. Ẹyin ẹ kàn kọ̀wé ranse sí ...
Read More
Ìdí tí àwọn ènìyàn fi pa Alfa Salami lórúkọ dà ní yìí
Oríṣiríṣi ogun, wàhálà àti ìdojúkọ ni ọmọ ẹ̀dá ń kọjú nílé ayé. Àwọn kan ségun, àwọn kan sì bogun lọ. Ore ọ̀fẹ́ Ọlọ́run nìkan ló lè gbé ẹ̀d...
Read More
Subscribe to:
Comments
(
Atom
)