Awon alase Olu-ilu Naijeria ti gbe opele ofin tuntun mi i sanle bayii, eleyii to n so wi pe " Paaki oko re ko si towo bapo ko mowo jade too ba fesu"
Bi o tile je wi pe awon olugbe Abuja so wi pe ona a ti fi ara ni awon ara ilu ni iru ofin bee je. Won ni pelu ofin abaadi yii, o kere tan moto kookan yoo ma san owo to to egberun merinla losu kan soso (14,000).
Dakun joo, ti o ba n relu Abuja mo paaki oko re ti o ba ti mo wi pe o ko ni senji lapo ko maa ba foju bale ejo lojiji. Amoran mi ko ju baun lo.
E se fun kopurasan!
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment