Smiley face

Ijakadi Ni Ilu Senegal

Awon Yoruba bo won ni airin jina lairi abuke okere, ti eniyan ba rin titi yoo ri ibi ti won ti n fodo ible jeun.

Ni ilu Senegal, okunrin nikan ko ni i dije ere ijakadi, atomode atagba obirin ni won kopa ninu ere naa. Ere ijakadi si je gbajugbaja ni ilu Senegal eyi ti n soni di olokiki ni inu naa.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment