Egbe agba boolu Nigeria ti a mo si Super Eagle feyin awon akegbe won tile Keyan gbole lana ode(5/6/13) yii ni ile baba won ni Nairobi. Idije ifesewonse elekeji pari pelu ami ayo okan si odo lati owo Ahmed Musa.
Nnkan bi osu meji seyin ni ifesewonse alakoko tani-yoo-kopa-ninu-idije-agbaye waye ni ilu Calabar nibi ti idije naa ti pari pelu omi (1-1).
Wayio, o ti wa foju han bayii wi pe ile Naijeria yoo kopa ninu idi ere boolu agbaye ti o waye lodun to n bo ni ilu Brazil
Sent from my BlackBerry wireless device from MTN
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment