Smiley face

Leyin Ti Snoop Dog Yi Oruko Re Si Snoop Lion, O Tun Ti NJe Oruko Tuntun Mii Bayii.

Laaarin odun kan ti Baba Alaja ti oruko re n je Snoop Dog yii oruko re pada si Snoop Lion, omokunrin naa tun ti yi oruko re pada si Snoopzilla bayii.

Won ni eyi ni i se pelu igbelaruge ise orin re tuntun to fe jade.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment