Smiley face

Omo Ayefele Meta Salo Ni Ilu Amerika

Nje e ti gbo?

A ni awon omo Ayefele bi meta ni won salo leyin Ayefele ni ilu Amerika.

O ti to bi ose melo kan seyin ti oba tungba ti gbe orin yide gbogbo ilu Amerika, sugbon o seni ni kayeefi wi pe Olayinka pada wa sile lai mu meta ninu awon omo re dani wale.

Awon meta ti won salo naa ni Ojoyido Adegbenga Ezekiel, SolomonOlugbenga Motimoke(Yatty) ati Olusola Kayode Isaac.

Ayefele ti fi to awon alase ilu Amerika leti, won si ti ni ti owo ba te won bi eru hausa ni won yoo se ju won pada wa sile.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments:

  1. Itiju nla ni eleyii je . Sio won lai. Kini won sa fun. Poverty mentality se wa lara won. Oro won dabi elede ti wo aso fun ti won se loge. Inu erofo naa lo maa pada si

    ReplyDelete