Latari ategun nla to n fe gbogbo ile ati dukia danu ni ilu Philippines, awon eniyan bi egberun mewaa ni won ti koja sorun airotele bayii.
Isele buruku yii ti je ki gbogbo nnkan di fopo-moyo. Joojumo ni awon ole n lo kaakiri lati ja awon eniyan lole ti ko si si olopa ti yoo da won lekun ise ibi owo won.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment