Ni nnkan bi ago kan osan ana ni awon olopa ilu Cotonou gbe okan lara awon olori omo agbegbon nigba kan ri, Alhaji Mujahid Dokubo-Asari ni ilu Cotonou to je olu ilu Benin Republic.
Gege bi a se gbo, Asari ki i se alejo ni ilu Cotonou, bo se ni ile ni ilu naa lo tun ni okoowo (okunrin naa ni ile iwe Ifafiti nibe) ki i si se wi pe boya won ka ise ibi kan mo lowo ni awon asiko ti awon olopa mu un.
Gege bi atejade agbejoro re, Festus Keyamo se so. O ni ko maa lo je wi pe awon oloselu kan ni ile Naijeria ni won lo ledi apo po mo ijoba ilu Benin Republic lati gbe okunrin naa pamo tori eto idibo odun 2015 to n kan ilekun gbongbon.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment