Bisoobu ti ijo Anglican ti ilu Eko nigba kan ri, Peter Adebiyi ti so oju abe nko.
O ni a fi taa ba n pe dudu ni funfun fun ara wa nikan ni taa ba n so wi pe okan soso ni Naijeria. Ko ba kuku san ki olomu da omu iya re gbe , ki onikaluku se owo ti e lotooto ko le mo iye ere to je.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment