Smiley face

Irawo Bamanga Tukur Ti Ja Sile Loju Orun




Leyinoreyin. alaga fun egbe PDP lapapo, Alhaji Bamanga Tukur ti pada kowe fi ipo re sile leyin opolopo fitinati ati ifooro.


Bi Bamanga ko tile ko iwe fi ipo re sile, awon agbaagba egbe PDP pelu iranlowo tabi ka so wi pe atilehin Aare Jonathan ti setan lati yo bi eni n yo jiga ni ola ode yii.

Sugbon ko le wa ninu akosile wi pe ki i se wi pe won yo ni, fun ra re lo ko iwe fi ipo re sile ni baba fi da bi ogbon.
Awon Yoruba ni taa ba n sare ki oju ma tini, ti oju na ti tini; are ka ma ku lo de tun ku.
.

Irawo Bamanga Tukur pada ja wa le  loju orun!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

1 comments: