Smiley face

Ogun To Daju Ni Ito Maalu Ni Ilu India



Ni ilu Naijeria, ti eniyan ba mu igo maltina meji  pelu a miliki kan, awon omo Naija gba wi pe ogun eje to daju to kosi laye.
 
Sugbon ni ilu India, bi eniyan ba ji to ba mu koopu ito maalu kan pere, ogun gbogbonise to daju ni. Won ni koopu ito maalu ti ko ba ti bi omo eleyii to jade lara re ki oorun to o yo le wo orisiirisii aisan bi Jejere, efori tuulu, Iko gbofunfun, Eje riru, Ito suga ati bbl. 
 
Orisii asa yii wopo laaarin awon elesin Hindu nitori won gba wi pe Orisa ni Maalu je kii se eranko lasan. 



 

 



 
 
 
Ogun eje to daju ti Naija

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment