
Sebi won ni ilu ti ko sofin, ese ko si nibe. To ba ti n fi siga SM see faaji l'Eko Fasola tele tabi siga Bensin niwo fi n segbadun l'Oshodi, o ti di ese bayii ni Ipinle Eko.
Ewon odun kan pere ni pelu ise aseelagun tabi ko san owo itanran bi Egberun Meedogun (15,000) owo naira Naija. Ba kan naa ni agbalagba onimukumu ko gbodo fa siga niseju omode ti ojo ori re ko ti to mejidinlogun (18yrs).
Ko to di wi pe yoo di gobe ni mo fi ni ki n sare fi eti yin to ofin tuntun naa. Mo wi i re abi mi o wi i re?
Eko o ni ba je ooo!
0 comments:
Post a Comment