Smiley face

Ti Mo Ba Ni Agbara, Gbogbo Musulumi Ati Kristeni To Wa Ni Naijeria Ni Maa Pa Pata- Kola



 
Oro awon Yoruba ni, emi ko ni mo so bee rara.

' Eni a foro lo to ni toun ba je. E gbo, kini koloro o se gan-an?'

Lehin igba ti Aare Jonathan ti towo bo iwe abadofin eleyii to gbogun ti ibalopo okunrin si okunrin ati obirin si obirin lati so di ofin ati ese fun irufe awon eniyan ti won ba da iru e lasa ni aimoye awon eniyan lagbaye ti bere si ni bu eni ate lu ile Naijeria to je ilu Ogo fun ile Adulawo pata.

Lara awon eniyan yii ni Kola Boof omo ilu Ijibiiti sugbon ti orirun re se lati ilu Sudan. Onkowe aroko ni Kola Boof, ilu Amerika lo si tedo si. [E le mo nipa Kola Boof si]. Eyin naa wo ohun to so kale...

 









Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment