Smiley face

Asiri Ogbon Tuntun Ti Won Fi Gbe Ogun Oloro Heroin Wole Ti Tu

Awon ajo NDLEA (National Drug Law Enforcement Agency) ti ilu eko ti won n sise ni papako ofurufu Murtala Muhammed International ti se awari ogun oloro (heroin) eleyii ti awon eniyan ibi kan ko pamo sinu eni-ikirun awon musulumi, eleyii ti won ti ju segbe kan ni papako ofurufu naa.

Ogun oloro bi kilo marun-un yii ni NDLEA so wi pe ati ilu Pakistan ni won ti n ro idan naa bo sugbon apa awon eniyan ibi naa jabo latari ayewo finifin to waye fun oko ofurufu Qatar Airline to gbe won wole eleyii lo mu won ju ogun oloro naa danu ni kiakia.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment