Smiley face

[Foto] Se Ago Olopa Ni Tabi Buka Alamala Dudu Pelu Obe Gbegiri?

Ago olopa kan re to wa ni agbegbe Eupi Otukpo ni ipinle Benue. Bi o tile je wi pe yoo soro fun opolopo lati gbagbo, sugbon ohun to daju ni wi pe otito oro ni.


Ilu Naija lawa, orisiirisii lo n sele. Aimoye ohun ti eniyan ko lero lo si tun le sele pelu.

Naijeria ilu mi, ilu ogo!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment