Smiley face

Kilode Ti Aare Fi Yo Lamido Sanusi?


Kilode ti Aare fi yo Lamido Sanusi loye gege olori Banki Naijeria ti a mo si CBN? Se ki i se tori owo epo $20bn ti okunrin naa kede fun gbogbo ilu wi pe o poora ninu apo owo ijoba?

Abi okunrin yii ko kaju osuwon to ni won fi yo loye bi eni yo jiga?

To ba je wi pe ko kaju osuwon, ki lo mu gba ami eye olori banki orile-ede to fakoyo julo ni odun 2010 gege bi Iwe iroyin Banker Magazine agbaye se kede re?

Gbogbo eniyan ni won so wi pe bi won se yo Sanusi mu ifura dani. Aimoye ibeere lo si ti n bimo ibeere kaakiri tibu-toro Naijeria lati igba ti won ti ro Sanusi loye.

Kilode ti Aare fi yo Lamido Sanusi loye?
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment