Smiley face

Mo Ni Agbara Lati Da Lamido Sanusi Duro- Aarẹ Goodluck Jonathan

Bi ọ tilẹ jẹ wi pe Aare Goodluck sọ ninu àpérò to waye lonii wi pe oun gẹgẹ bi Aare ni agbara lati da Lamido Sanusi to jẹ olori banki ilẹ Naijeria duro, oni sibe ki i se wi pe awon da duro. Aarẹ ni awon kan ni ko lọ rọọ́kún sile fun ìgbà kan naa ni ki awon iwadii abẹnu kan le waye ni ẹ̀ka banki apapọ ilẹ yii. Oni ti iwadii naa ba fẹnu sọlẹ ti Lamido kò ba lẹ́bọ lẹ́rù dandan ni ki awon daa pada sori aga oye rẹ̀.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment