Ọkunrin kan lo sọrọ ti mo si ri ọgbọn ninu ọrọ rẹ. Oni ÌMỌ̀ lo jẹ fun eniyan lati mọ wi pe ara fruit ni Agbalumọ mo. O sugbon Làákàyè lo jẹ fun eniyan lati mọ wi pe agbalumọ ko ye ko wa ninu Fruit Salad. Bi eniyan ba tilẹ n fi ounjẹ dara, njẹ a le pe iru eyi ni ara to ba oju mu bi?
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment