Odun onihoho waye lonii ni ilu Okayama to wa ni Japan ti won pe ni Hadaka Matsuri nibi ti awon okunrin bi egberun mesan (9,000) ti n tiraka ati mu igi ori ire.
Igi ori ire ti won maa n ju ni ile orisa Saidaiji nibi odun Hadaka Matsuri yii ni won gba wi pe eni to ba mu igi naa yoo ri ire ati ayo ninu odun.
Ki awon eniyan to kopa ninu odun yii won gbodo ti koko ti lo se iwe mimo, ki won si wo aso funfun kekere kan lati bo idi won.





0 comments:
Post a Comment