
Oloye Inengite Nitabai to je bi egbon si Aare Goodluck Jonathan ti awon kan jigbe ninu osu keji odun yii ti won si n beere fun obitibiti milionu ni a gbo wi pe won ti ko lati gba ogbon milionu owo naira (N30M) ti won fi n be won lati da okunrin naa sile. Owo ti awon agbe-ni-pamo yii n beere gan-an ni nnkan bi ogorun marun-un milionu owo naira ile wa eleyii ti won ni ko gbodo din sisi.
0 comments:
Post a Comment