Smiley face

Fidio: Awon Olopa Na Omo Naijeria Bi Ole Ni Ilu South Africa

Sebi ba se bi eru la se bi omo, awon Yoruba loni ibi ko ju ibi lo. Bi omo Naijeria tile gbe ni ilu ajoji, eleyii ko so eto re nu gege bi omoniyan. Eyin na e wo bi awon olopa ilu Sounth Africa se na omo Naijeria ni inakuna.
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment