Smiley face

Won Ti Lo Sin Lucy Si Akwa Ibom

 
Okan ninu awon eniyan bi ogun ti won se agbako iku ninu eto igbanisise ajo ti n ri si iwole-wode ile Nigeria (Nigeria Immigration Service), ti di eni ti awon ebi re ti lo sin ni ana ode yii. Arabirin Lucy ti awon ebi re salaye wi pe ilu Port-Harcourt lo n gbe ni awon ero te pa nibi papa eto igbanisise naa. Arabirin ti won lo n mura ati se igbeyawo ni won ti lo sin si ilu re bayii to wa ni Ipinle Akwa-Ibom.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment