Ariyanjiyan kan lo waye lori telifisan laarin awon oloselu kan ni ilu India. Gege bi a se gbo, opolopo awon eniyan ni won pe sita gbangba lati wo iran ariyanjiyan naa. Lojiji, ni okunrin kan jade wa laaarin awon onworan naa to si dana sun ara re. Igba to se eleyii tan lo dimo okunrin asaaju oloselu adugbo naa eleyii ti oun naa wa ni agbegbe iworan naa.
'This man suddenly came on the stage, poured petrol on himself and set himself on fire before tightly hugging one of the political guests.People were just too shocked to know what was happening,Two other local politicians taking part in the show, Ram Kumar Singh and Chowdhary Hriday Ram Verma, sustained minor burns while trying to save the pair.
'The injured were first admitted to the district hospital here (in Sultanpur) and were then referred to Lucknow.Singh sustained burns on 95 per cent of his body which doctors say are likely to be fatal, while Fauji was in critical condition with 75 per cent burns.'
Kamruzzama Fauji ni eni ti won dimo.
Olayemi Oniroyin ni eni ti o kede isele naa faye gbo.
Rere Run o!
0 comments:
Post a Comment