Smiley face

Olori Awon Ashewo Ilu Nigeria Lo Se Party Ajinde


Cossy, ojulowo omobirin onise nabi ile Naijeria lo se pati ajinde lale ana pelu awon isomogbe re ni ile ijo. Ise asewo ti ni oba bee lo ni ijoye ni ilu Nigeria.

Oju kii ti won mo, gbogbo opportunity ni won fi n pate oja to kowo lori. Won ni to ba je wi pe arugbo lo n se ise ashewo ni ilu Naijeria, awon omo jaye-jaye so wi pe Cossy l'Oga Nla. To ba je aro ti ko le rin lo n gbele pawo, awon ti won mo bo se n lo so wi pe Cossy naa ni oga-oga ti won pe ni Mama Nla.

Afikun: E maa gbagbe wi pe omobirin yii n ya fiimu aworan onihoho lowo eleyii to tun ni 'kerewa' ninu. Fiimu yii ko ni pe di ohun ti won yoo fon kari aye lai pe.

Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment