Smiley face

Paul Okoye: A Ti Kekere Ni Musulumi Ti N Ko Omo Re Ni Keu

Ni ile Yoruba ti eniyan ba se igbeyawo, awon eniyan won yoo bere si ni se adura wi pe ere to po ni toko-taya yoo je nibe. Sugbon nipa ti Paul ati iyawo re ti won se igbeyawo laipe yii, Edumare ti fi ere si ajosepo won saaju ki igbeyawo to waye.

Paul gbe omo re wo inu omi lonii, lati bere si ni ko omo naa bi eniyan se n we ninu omi. Sebi ati kekere ni Musulumi ti n ko omo re laso.

Adun to n dun mo wa ninu ko ni ba wa lokan je. Gbogbo eni n wa omo rere Eduamre ba wa dun won ninu. Amin
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment