Smiley face

Asiri Tu: "Obasanjo Ko Lo Wole Lodun 1999, Madaru La Fi Gbe Wole" Ta Lo So Bee?

Ninu ipade National Conference to n lo l'Abuja ni okan lara awon ti n soju Goosu Iwo-oorun, Senator Femi Okurounmu ti gbe la oro naa mole wi pe 'idibo to gbe Obasanjo wole lodun 1999, eru la fi se'.



Won n fi owo bo okunrin naa lenu wi pe won kii so iru oro bayii nigbangba. Sugbon kaka ki Okurounmu sinmi agbaja n se lo tun gbohun soke bi akigbe ilu Oyo.

"Obasanjo did not win the election, he
was anointed by the powers-that-be to pacify the South-West over the annulment of June 12 elections. What I said, I have said it to his hearing."

Gege bi oro re, o ni awon alagbara lo agbara won lati fi bi won se yan Obasanjo sipo re awon eniyan ti won n gbe ni Goosu-Iwo-oorun lekun latari bi won se padanu June 12 ti Oloogbe Emuke Abiola.

Okunrin yii tun so wi pe ko ni dara ki awon alagbara eto iselu maa fari apa kan dari apa kan si, eto ise ijoba Nigeria gbodo di ohun ti yoo kari lai se madaru. Iru awon ofin to ti igbese naa leyin si gbodo wa ninu iwe ofin ile Nigeria.

"Obasanjo was not the best candidate in the 1999 contest, but Nigerians decided to give it to the South-West for what happened to the late Chief Moshood Abiola.

Nigeria has never had the best as its president.

"Our greatest problem is fear and suspicion and that is why we want everything to be in the constitution.

Then if we want zoning, we should
zone the presidency to all ethnic nationalities in Nigeria so that all of them will enjoy the presidency."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

3 comments:

  1. This man is Mad......Fø̲̣̣я̅ H̶̲̥̅̊۞w̶̲̥̅̊? Many years now.....Nonsense, I hope u don't have U̶̲̥̅̊я̩̥̊ share in dat government.....you better go and spend your confab share with your children

    ReplyDelete
  2. Ofcause,he's a real mad man he knows all this for all this while...that's nija,stupid goverment...and that mad man he's unimportant!!!

    ReplyDelete