Smiley face

"Eni Ba Dale Yoo Bale Lo" Yinka Ayefele

Sebi ti ina ko ba tan laso eje kii tan leekanna ni owe awon Yoruba wi.

Opolopo awon eniyan ti won ba mo Olayinka Joel Ayefele lati ibere pepe yoo mo wi pe sorosoro to gbamuse ni.
Eniyan ti ko ba sile ronu jinle nipa igbe aye eda ati akiyesi awujo ko le soro ta ko pawo gidi.


Ede oro atata naa lo pada bi orin ti won pe ni 'Tungba Gospel' ti MON fi n pawo kaakiri agbaye.

Ayefele fi ero ijinle ko apileko kan eleyii to pe akole re ni "Judas Iscariot". Mo le ro wi pe e o gbadun re gidigidi.

Apileko naa ni yii:

"Betrayer is a gang up• It is not a single mind action but collaboration of envious people•

The repercussion at the betrayer side is regret and apology, but the deed has been done and it is always painful to the bone•

If care is not taken at time could lead to serious illness or death particularly when a lot of investment is done on the betrayer•

May God help us•

One is bound in ones life time to be betrayed one should be careful not to rely on people too much•"


Mmmmmh! Omo Ayefele ko daruko eniboodi, Olayemi Oniroyin gan-an ko si so wi pe enikan bayii ni OJA n baawi. Sebi arojinle to wa lati inu opolo iriri eda nipa igbe aye awon eniyan lasan ni.

E ku ojulona fun apa keta fiimu yii!
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment