Okiki ati ariwo gba ilu Ake lojo ti omo Olusegun Aremu Obasanjo, Damilola Obasanjo se igbeyawo Alarinrin. Igbeyawo yii waye laaarin ojo kesan-an ati ojo kewaa osu yii pelu ololufe re, Tope Borishade. Omo ni adun igbeyawo, adura wa ni ki Edua oke wa ba fi adun si ife won. Amin
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment