Oga agba awon omo ologun ti ilu Amerika fi ranse si ilu Nigeria, Gen. Mark Welsh III ti so niwaju igbimo teekoto to n ri si awon oro okeere wi pe ise awon lati wa awon omo ti Boko Haram jiko ko easy rara nipa wipe awon omo ologun Nigeria n beru iku, won si n fi ogboogbon fadi seyin bi igba eniyan n jo skelewu.
"We're now looking at a military force that is, quite frankly, becoming afraid to even engage.
The United States doesn't have the capacity, the capability to go rescue every kidnapped person around the world."
Okunrin yii so wi pe iranlowo lasan ni ile Amerika le se, ati wi pe eleru gan-an lo ye ko gbe kaya re nibi to ti wuwo. Sugbon ko ri bee pelu awon omo ologun Nigeria. Awon nnkan bee si n ko irewesi ba awon iko ologun ilu Amerika.
Iwe iroyin kan ni ilu Amerika si ti gbe jade wi pe oseese ki ilu Amerika gan-an sempe ti iru awon iwa bayii ba n tesiwaju laaarin awon omo ologun Nigeria. Iwe iroyin New York Times tile so wi pe o seese ko je wi pe iwa jegudujera to ti ba Ilu Nigeria je lo fa sababi.
0 comments:
Post a Comment