Bi iroyin isele ado oloro Boko Haram to dun ni Jigawa se n wole bee naa ni ariwo ado oloro iku dun ni Baghdad ni orileede Iraq nibi ti awon eniyan bi ogbon ti doku ni yajoyajo. Awon Soja bi meta lagbo wi pe awon Boko Haram de pakute iku le fun lonii ni Jigiwa nigba ti awon bi meta mi farapa.
Lati inu iwe Iroyin Leadership
Ekunrere iroyin bo laipe.
0 comments:
Post a Comment