Smiley face

Iyawo Ronaldo Bora Sile Ja Nitori Oro Nigeria

Irina Shayk to je iyawo ogbontarigi agbaboolu agbaye, Christiano Ronaldo naa ti wi pe aisi nibi ni aibani dasi. Lori oro awon omo ti Boko Haram ji ko, dandan ni ki won da awon omo naa pada ni kiakia.

#BringBackOurGirls


Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment