Smiley face

"Olorun Ti Keyin Si Fayose Lo Se Subu Yakata Nibi Ipolongo Idibo Re To Waye" -Gomina Fayemi


Isele kan sele lose to koja nibi ti ori oke ti Fayose duro le to fi n polongo eto idibo re dawo lule lojije. Isele yii ni Gomina Ipinle Ekiti se alaye re gege bi apeere wi pe Olorun oba gan-an keyin si Ayo Fayose ati egbe PDP.

Oro yii lo so nibi ipade kan to waye ni ilu Eko pelu Ogbeni Rauf Aregbesola ti Ipinle Osun nibi won ti gbe n se eto ikowojo fun eto ipolongo idibo won.

Won sai menu ba eto idibo to n bo lowo ni Ipinle Osun ati Ekiti.

"We will go to any length not only to ensure that the votes of the people count but that the votes must be counted at the spot where they have
chosen to elect the leader for themselves and we will do everything to ensure that INEC is forced, not just encouraged to use the card reader for
these elections in Ekiti and Osun."
Share on Google Plus

About Olayemi Oniroyin

0 comments:

Post a Comment