Nnkan sele niju e ko gbo letile. Oluko ile iwe girama kan, Ellen Niemiec to wa ni South Carolina ni ilu Amerika la gbo wi pe o ba awon omokunrin ile iwe re lajosepo lojo kan soso.
E yii ni atejade ile iwe naa:
"South Carolina high school teacher Ellen Niemiec, 29, is accused of sexual battery for allegedly having sex with three of her students on the same day.
"The Cross High School instructor has been placed on administrative leave and is banned from the campus in Berkeley County, eyi ni atejade awon alase ile iwe naa.
"Multiple sexual encounters took place on April 11 during a house party and on the school's grounds."
Omo odun mokandinlogbon(29) ni Niemiec, o si ti bimo meta. Lara asiri re to tu si awon alase lowo ni wi pe obirin naa tun ya foto ihoho re ranse lori foonu si okan lara omo ile iwe re nibi to ti yadi sile lai wo pata.
Chai! Chai!! Chai!!! Dariz God oooooo
0 comments:
Post a Comment