Ile nla kan ti a mo si Triana Building to wa ni agbegbe Apapa gbana je laaaro oni (25-06-14) nibi ti dukia to to aimoye milionu ti sofo danu.
Bi o tile je wi pe awon osise panapana Ipinle Eko debi isele ijamba ina naa sugbon ina yii ti ba n kan je jina ki won to foju han.


0 comments:
Post a Comment