
Ni agbegbe Onipanu ni oju ona to lo si Oshodi to wa ni ilu Eko ni Awon Soja ti gbe fa ibinu yo ni aaro oni [4-7-14] nibi won ti sun awon oko akero BRT ti Fasola. Isele yii waye latari okan ninu awon oko BRT naa to kolu Soja kan ti Soja naa si ku tue bi adiye agiriki ti won ko sinu otutu. Isele to sele re e ti awon soja fi lo digun wa ti won si bere si ni soro bi ageku ejo.

Sugbon nipa ti oko BRT ti won dana sun, oga awon Soja ni Yaba ni awon ko ni awon sun moto Fasola, o ni boya awon omo ijoba (awon omo ita) ti won sun abe biriji ni won sun awon moto ijoba naa.

Ninu alaye re to se, oni oseese ki soja naa ma ku to ba je wi pe won tete gbe lo si osibitu ni. O ni sugbon awon ara Eko daju Soja naa dele ti won si n korin tobaleku-koku-danu. Die ni yii ninu alaye ogbeni Rightman Ogeh to je okan lara awon oga soja ni Yaba:

"A soldier, who was passing through the bus stop, saw the soldier and called the office because he could recognise him. By the time we got there, we realised that our colleague was inside the bus already dead.

“They said it was a BRT bus that knocked him down. He was riding a licensed motorcycle. So, why was he not taken to the hospital until he died? Of course, our men were angry and we decided that no BRT bus would be allowed to pass through the road. We did not stop others.”

“When things like this happen, you will hear different versions, but I can tell you that soldiers did not burn the busses. It is possible that some area boys carried out the act. No one was harassed by soldiers; we only stopped some people who were taking pictures and wanting to film the area.”

Awon eniyan ti isele naa soju won je kari gbo wi pe ohun ti soja naa mo o je lo yo. Won ni irin taani-yoo-mu-mi ni soja naa n rin loju ona to je ti oko BRT nikan, ko to di wi pe won fun ni igbega lati lo tesiwaju ise soja lajule orun nibi ti ko ti si iberu Boko Haram.


posted from Bloggeroid
0 comments:
Post a Comment