Awon omo ogun agbebon ti won n je Al-Shabab ti won n yo ilu Kenya lenu
ti pada kolu ago olopa to wa ni Gamba ati awon agbegbe mii nibi ti won
ti pa awon eniyan bi ogbon ti won si dana sun aimoye dukia eleyii ti
soosi ile Oluwa wa lara re.
Subscribe to:
Post Comments
(
Atom
)
0 comments:
Post a Comment