Awon osere n sise lowo, MAMA EREKO ni won pe akole eleyii. A ri Afeez Eniola, Afeez Abiodun ati Niyi Johnson; bee aimoye osere mii ni won tun jo wa lenu ise aje ti won. Ki Edumare je ki gbogbo wa se asejere. Amin.
E joo, e lo ni won ta moimoi elepo ladugbo yin na?
Oga mi, moimoi ke losan awe. Se e fe so awe yin ni tabi e fe ja sonu?
ReplyDelete